IFI'PA BA'NI LO PO ati ohun ti a le se si - ni a ko lati tu awon okan ti o ti gba ogbe ati awon ti o ti subu sinu isele yii, ninu, lati je ki won mo bi won ti se le bori isoro isele yi. A tun ko iwe yii lati mo oniruuru ohun ti o nlo ni okan awon okunrin, idi fun ifipa ba'ni lo po, ati lati la oju awon eniyan si iwa yi, ki won si mo bi won ti se le dena re, nipa bee, awujo wa a le wu ni lati gbe. |

|